One Nation, Four Hundred Languages
Unity and Diversity in Nigeria's Language Policy
SOMMAIRE Une nation, quatre-cents idiomes: Unité et diversité dans la politique linguistique du Nigéria Cet article traite des politiques linguistiques du Nigéria, de leurs objectifs contradic-toires, de leurs motivations et de leurs orientations idéologiques. Ces conflits s'expliquent en fonction du deVeloppement socio-historique de la nation, de son paysage ethnolinguis-tique complexe et de l'incompatibilité des exigences "nationalistes" et "nationistes," le pays essayant de maintenir un pluralisme linguistique et culturel tout en préconisant l'unification linguistique et l'intégration nationale. On indique que les constatations faites au Nigéria révèlent certaines tendances qui se répètent de facon identique dans d'autres pays du Tiers Monde. À RÒKO YÍ NÍ SÒKÍ OrÍlè èdè kan, irinwo èdè: lrépo ati aìsepò tí 6 wa nínu ìlana èdè lilò ní orílè èdè Naìjíría Aroko yí ni abayorí ìwaadí lorí ìlana tí ìjoba orílè èdè Naìjíría gbe kalè lorí èlò oníruuru èdè tí ó wa ní ìgbèríko rè. A rí ì wípe òtòòtò ní ìpínlèsè awon ìlana naa; won kò sì korí sí ibìkan naa rara. Iwaadí tun fi í han wípé ìkòyìnsíra awon ìlana wonyíí kò saì ní í se pèlu ìtan ìdagbasókè orílè èdè Naìjíría, oníruuru èdè tí ó wa nínu orílè èdè naa, ati ìyanju tí ìjoba ngba lati so orílè èdè naa pò labé èdè kan bí ó ti nse akitiyan láti fúun awon orísirísi èdè tí 6 wa ní ètó ati ìtóju tí ò ye. Ìsòro míran tun wa pèlú: òtò ni èdè tiwa-n-tiwa, òtò ni èdè tí 6 wúlò gidi fun akóso orílè èdè ati èkó kíkó ní ilé ìwé. Ní ìparí, ìwaadí yí fí ye wa wípe ohun tí 6 nselè ní orílè èdè Naìjíríà k6 yatò pupò sí ìrírí awon orílè èdè tí 6 sèsè ndagba s'ókè. RESUMO Unu nacio, kvarcent lingvoj: Unueco kaj diverseco en la lingvopolitiko de Nigerio La artikolo ekzamenas la lingvajn politikojn de Nigerio laǔ iliaj kontraǔaj celoj, ideolo-gial motivigoj kaj orientiĝoj. Gi klarigas iliajn kontraǔdirojn en la kunteksto de la soci-historia evoluo de la nacio, ĝia komplika etnolingva pejzaĝo, la konfliktaj postuloj de "naciismo" kaj "nacio-ismo" kaj la klopodo konservi lingvan kaj kulturan pluralismon dum oni samtempe apogas lingvan unuiĝon kaj nacian integriĝon. La aǔtoro argumentas, ke la konkludoj el Nigerio malkasas certajn tendencojn, kiuj reaperas en aliaj Triamondaj landoj.
https://doi.org/10.1075/lplp.13.2.03aki
Cited by
Cited by 27 other publications
This list is based on CrossRef data as of 21 january 2023. Please note that it may not be complete. Sources presented here have been supplied by the respective publishers. Any errors therein should be reported to them.